Tope Alabi

Download Mp3: TOPE ALABI – OLUWA O TOBI (Video Lyrics)

Download Mp3 TOPE ALABI OLUWA O TOBI Video Lyrics

Oluwa O Tobi Mp3 by TOPE Alabi

Play Audio

Oluwa O Tobi Lyrics – TOPE Alabi

Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi

Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
Pupopupo ni O, O koja omi okun at’osa, O ga po
Ajulo O o se julo

Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa
Oba lori aye, O tobi o eh
Agba’ni loko eru, Olominira to n de’ni lorun
O fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka
Olugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segun
Akoni ni O o
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi
Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi
Oluwa

Download Mp3 TOPE ALABI OLUWA O TOBI Video Lyrics

Rate this post

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button
%d bloggers like this: